BVAS: Àwọn oníròyìn gbóṣùbà fún Àwọn aláàkóso Àjọ elétò Ìdìbò Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà
Bí àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà ṣe ń duro de abajade idibo ààrẹ ọjọ́ Sátidé, Díẹ̀ lára àwọn oníròyìn ti o wa kọ̀ròyìn ìdìbò ní Daura, Ipinlẹ Katsina, níbi ti Ààrẹ Buhari ti kopa ninu eto idibo sọ pe Igbimọ Àjọ elétò Ìdìbò Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà(INEC) ti ń ṣe dáadáa.
Ọ̀kan lára àwọn Akòròyìn naa sọ fun Oniroyin VON, Timothy Choji pe lilo ẹ̀rọ BVAS ti mu idibo Ààrẹ ọdun 2023 rọrùn pupọ.
Ọláyinká Akíntọ́lá.
Leave a Reply