Alábòjútó Ìdìbò tí Àjọ EU (European Union) tí gbóríyìn fún àjọ élétó ìdìbò INEC àti àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ ní Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà fún ṣiṣakoso ìdìbò tó múná dóko ní ọdún 2023.
L’ẹnu Olórí kàn nínú àwọn ìgbìmọ̀ EU náà, Ọ̀gbẹ́ni Deleen Michel, ló sọ èyí níbí ifọrọwanilẹnuwo pẹ̀lú àwọn òníròyìn ní ilé akojọpọ ìbò INEC ní Surulere, Ìpínlẹ̀ Èkó, ní ọjọ́ Àìkú.
Michel lọ sí àgbègbè Oworonshoki ní ìlú Èkó ní ọjọ́ Àbámẹ́ta pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀, kò tó wà sí Surulere, ó sọ pé ẹgbẹ́ òún kó rí ibi tó kù díè káàtó ní gbogbo ibí tí àwon ṣàbẹwò sì.
Àjọ EU náà ló ràn àwọn olúwoyé bí ọgọrùn (100) lọ sí gbogbo ìpínlẹ̀ mẹ́rin-dín-logójì (36) àtí Olú-ìlú, Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Lekan Orenuga
Leave a Reply