Lẹyin ti Ọ̀mọ̀wé Akeem Olawale Lasisi (Ààrẹ aṣakojọpọ ní Ìpínlẹ̀ Ekiti) ka ibo tan, Ẹgbẹ oṣelu APC lo jawe olubori ni Ìpínlẹ̀ Ekiti pẹlu ibo 201,494
Èyí ni èsì gbogbo ìbò Ìpínlẹ̀ Ekiti
Ijọba ibilẹ mẹrindinlogun lo wa ní Ìpínlẹ̀ Ekiti
Àwọn to forukọsilẹ: 987,647
Àwọn ti wọn fọwọsi: 315,058
Ẹgbẹ Oṣelu àti Ibo wọn:
A- 69
AA -29
AAC – 108
ADC – 1,337
APC – 201,494
APGA – 268
APN – 46
APP – 91
BP – 46
LP – 11,397
NNPP – 264
PDP- 89,554
SDP-2011
YPP – 81
ZLP – 460
Ìbì tí wọ́n gbà : 308,171
Ìbò tí wọ́n kọ̀ : 6301
Ìbò Lápapọ̀: 314,472
Leave a Reply