Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí ń darí ìpàdé ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 337

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ń darí ìpàdé ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀ ní gbọ̀ngàn ìgbìmọ̀,ní ilé-iṣé Ààrẹ,Villa ní  Àbújá.

Àwọn tí ó wà níjokòó níbẹ̀ ní Akọ̀wé fún ìjọba àpapọ̀,Ọ̀gá àgbà Mustapha àti Ọ̀gá àgbà fún àwọn òṣìsẹ́ ìjọba àpapọ̀, Dókítà Fọlásadé Yẹmí-Ẹ̀san.

Àwọn tó tún wà níbẹ̀ ní Mínísítà fún ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti Àṣà, Lai Mohammed, Ìdájọ́, Abubakar Malami, ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti ọrọ̀-Ajé lórí ayélujára, Isa Pantami, Ìnáwó, Ìsúná àti ìṣètò orílẹ̀-èdè, Zainab Ahmed, Olú-ìlú, Mohammed Bello àti Ẹ̀kọ́, Adamu Adamu.

Àlàyé lẹ́kùúnrẹ́rẹ́ nígbà míràn….

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button