Adarí àti Alága ajàjàngbara ti ilẹ̀ Yorùbá tá n tún pè ní ” Ìlànà Ọmọ Oòduà Worldwide” , Wálé Adénìran ti kọ̀wé fipò rẹ̀ sílẹ̀ látàrí ìṣe owó ìlú básubàsu àti ìkówójẹ.
Adénìran sọ wípé òun se èyí láti jẹ́ kí àwọn àgbààgbà ẹgbẹ́ leè rí ọ̀nà tó pọ̀ láti wádìí òun bóyá òótọ́ wà nìdìí ọ̀rọ̀ yìí.
Ó pe ìpènijà ẹnikẹ́ni láti wádìí òun tàbí wọ́n rí òun tí òun gba owó àìtọ́, kí ẹni náà bọ́ si gbangba Kó wà wí tirẹ̀.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply