Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ Àgbáyé Àwọn Eléré ìdárayá Tí Dínà Mọ́ Àwọn Eléré Kenya Mẹ́ta Kàn

0 197

Àwọn eléré ìdárayá mẹ́ta tí Kenya tí ní idinamọ fún àkókò àpapọ̀ ọdún mẹ́jọ lẹ́yìn tí wọ́n kùnà níbí ìdánwò oògùn – doping.

Ẹ̀ka Athletics Integrity Unit (AIU) tí fi òfin dé aṣáájú eléré-ìje Alice Jepkemboi Kimutai ati Johnstone Kibet Maiyo fún ọdún mẹ́ta, àtí eléré-ìje Mark Otieno fún ọdún méjì.

Otieno, ẹní ọdún mọkandinlọgbọn, kùnà níbí ìdánwò anabolic steroids Methasterone kí o to bērẹ̀ èrè ìje 100m nibi Tokyo Olympics Game. O túmọ sí pé wọ́n kò gbàá láàyè láti dije.

Otieno, ló ti gbà ìdíje National Champion 100m ní ìgbá mẹ́ta ọtọtọ, ní òfin náà tí dé láti ọdún tó kọjá tí yóò sì parí ní Oṣù Keje ọdún 2023.

Kimutai, ẹní tí o kùnà níbí ìdánwò fún “Male hormone testosterone – bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kẹrindilogun Oṣù kọkànlá ọdún yìí.

Idinamọ Maiyo bẹ̀rẹ ní ogunjọ́ oṣù keje fún bí o ṣé kùnà lórí ìdánwò erythropoietin (EPO).

Mínísítà fún èrè ìdárayá tí Kenya Ababu Namwamba lẹhinna kéde pé wọ́n ti pinnu láti pé ẹnikẹni tó bá tún kùnà ìdánwò ní ọdaràn “doping” níbí àwọn èrè ìdárayá ní ìgbìyànjú láti mú òpin bá àwọn ọran nínú èrè ìdárayá.

Lekan Orenuga

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button