Take a fresh look at your lifestyle.

US Àtí Iran Fí Iga Gbágà Lori Bí Russia Ṣé Ń Ló Nǹkan Ìjà Ògún Iran

0 260

Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà àtí àwọn ọrẹ rẹ̀ pẹlu Iran, Russia àtí àwọn ọrẹ rẹ̀ tí gbó ewúro sì ará wọ́n lójú lórí pé Tehran ń pèsè òún ìjà fún Moscow pẹ̀lú àwọn “dronu” tó ń kọlù orílè-èdè Ukraine – àtí pé AMẸ́RÍKÀ fí ẹsùn kàn Akọ̀wé àgbà UN bi “O ṣé fí ayé gbà Russia làti ṣé irọkẹ̀kẹ” àtí bí o ṣé kùnà Látí ṣé ìwádìí.

Aṣojú Iran ní UN Amir Saeid Iravani sọ pé, gbogbo àṣẹ tó kọ̀dìí Iran lábẹ́ UN látí tá òún ìjà ogún tí parí látí Oṣu Kẹwa ọdun 2020 àtí pé Amẹrika àtí àwọn ọrẹ rẹ̀ tó sọ́ pé Tehran nilo látí gbà àṣẹ” kò ní ẹtọ lábẹ́ òfin”

iravani tún tẹnumọ pé a kò gbé àwọn “dronu” lọ́ sí Russia fún lílò ní Ukraine, tó sí fí múlẹ̀ pé “àròsọ lásán ní tí kòsí fí ẹ̀ṣẹ múlẹ̀”… ó tèsíwájú pé, kó ṣí ìdí mìíràn tí wọ́n fí ń ṣé èyí jù látí darí àkíyèsí àwọn ènìyàn kúrò ní bí Amẹ́ríkà àtí àwọn ọrẹ rẹ̀ ṣé ńgbé àwọn òun ìjà oloro lọ́ sí Ukraine látí lé mú ìforígbárí náà gùn sí.”

Lekan Orenuga

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button