Take a fresh look at your lifestyle.

Faransé Npè Fún Àwọn ijiroro Láàrín Tùnísíà Àtí IMF

0 150

Ilé-iṣẹ́ Àjèjì Ìlú Faransé tí pépé fún ijiroro láàrín àwọn aláṣẹ Tùnísíà àti (International Monetary Fund) IMF pẹ̀lú èrò láti ṣé àdéhùn tún.

Ní àárín Oṣù Kẹwàá, IMF tí ṣé àdéhùn pẹ̀lú ìjọba Tùnísíà látí gbà láti máà tí sàn owó 1.9 bílíọ̀nù ní owó dọla Améríkà ní ìpele tó jẹ́ kó bẹ́rẹ́ látí Oṣù Kejìlá ṣé ìrànlọ́wọ́ fún Tùnísíà látí kojú àwọn ìṣòro ọrọ àjé tó ṣé pàtàkì tí ìgbìmọ̀ IMF sí tí fọwọ́sí.

Owó yiyá náà ní ìjọba tí gbèrò látí ṣé àtúnṣe ìdánwọ̀ owó oúnjẹ (food and energy) àtí àtúntò tí àwọn ilé-iṣẹ́ tí wọ́n ní àgbàrá.

Paris ṣé ìrántí pé o ṣé dandan “láìsí ìdádúró” àwọn àtúnṣe náà ṣé pàtàkì fún ìdúróṣinṣin àti ògo tí orílẹ̀-èdè náà, Anne Legendre ṣé ìdáhùn.

Ìròyìn sọ pé ibo ilé aṣòfin ní ọjọ́ Àbámẹ́ta pẹlú ẹrí (90%), òun idojuti fún Ààrẹ Kais Saied, tí àwọn alatako rẹ̀ sí ń pé fún kí Ààrẹ kúrò lórí alefa.

Lekan Orenuga

Leave A Reply

Your email address will not be published.