Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà Yóò Ríi Dájú Pé Àwọn Àgbẹ̀ Ní Àǹfààní Sí Okòwò Àti Ọjà Tó Yanrantí

0 270

 

Ìjọba Nàìjíríà sọ pé àwọn Agbẹ Ìgbèríko yóò ní àǹfààní sì Ọjà RAAMP fún kára káta lórí èrè oko wọ́n láti jẹ́ kí ìgbé ayé dẹrùn fún wọn àti láti dẹkùn òfo lórí ìkórè wọ́n.

 

 

Àǹfààní pọ ni janturu fún wọn, pápá jùlọ lórí ohunkóhun tí ó jọmọ okowo àgbẹ
Ìṣẹ Àkànṣe RAAMP tí wá ní ìpínlẹ mọkàndínlógún- Abia, Akwa-Ibom, Bauchi, Ebonyi, Ekiti, Gombe, Kogi, Katsina, Kaduna, Kano, Kebbi, Kwara, Ogun, Ondo, Oyo, Osun, Niger, Plateau àti Sokoto.

 

 

 

Olubunmi Adeyẹmọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button