Take a fresh look at your lifestyle.

Gbógbo Ẹkùn Ní Ìdojúkọ Omi Tí Ó Kọjáàlá Ni 2021

0 299

 

Gbógbo Ẹkùn ní àgbáyé ní wọ́n ní Ìdojúkọ Omi tí ó kọjá àlá ní ọdún tó kọjá, pàápàá julọ Omiyále àti Iyangbẹ-Ilẹ̀, ogunlọgọ ènìyàn ní wọ́n dojú kọ ìṣòro Omi ti ko mọ tó, igbimọ gbogboogbo ti orilẹ-ede Agbaye ló jẹ́ kí eléyìí dì mímọ.

 

 

Wọ́n rọọ àwọn Aláṣẹ láti yàrá ni wàrà ń ṣe sáá, ní kíákíá, kí ó wọ́n sètò lórí Di dẹ́kun tàbí dídin ̀Ọ̀da àti Omiyále lásìkò, kí a bàa lè dẹ́kun lórí òfo ìjàńbá Omi.

 

 

Olubunmi Adeyẹmọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button