Take a fresh look at your lifestyle.

Àtúnyẹ̀wò Ife Àgbáyé 2022: Ọjọ́ Kọkànlá

0 248

Ní Ọjọ́ Kọkànlá ní Ìfẹ Àgbáyé Qatar 2022, Ilé Akéde Nàìjíríà ṣe awotẹlẹ àwọn ere ti n bọ ti wọn ṣeto lati waye ni Ọjọ́bọ̀, lakoko ti àwọn ọmọ Áfríkà Tunisia ti n kojú ẹgbẹ́ agbabọọlu France nígbà tí Australia dojukọ Denmark ní Ìpele Kẹrin, ẹgbẹ́ agbabọọlu Poland yoo kojú Argentina tí Saudi Arabia yóò sì kojú Mexico ní Ìpele Keta mìíràn.

 

Ni Ọjọ́ Kẹwa, Senegal di ẹgbẹ́ àkọ́kọ́ ti Áfíríkà ti o tẹ̀síwájú sí àwọn ìpele jíjá kíákíá lẹhin ìṣẹgun àmi àyò méjì sí ẹyọkan pẹlu ẹgbẹ́ agbabọọlu Ecuador, nígbà tí Netherlands ti ọ pegede náà Ṣẹ́gun ìlú ti o gba wọn lalejo Qatar pẹlú àmi àyò méjì sódo. Ẹgbẹ́ agbabọọlu England náà tẹsiwaju lẹhin ti o na Wales ní àmi àyò mẹta sodo, tí AMẸ́RÍKÀ náà si Ṣẹ́gun ẹgbẹ́ agbabọọlu Ìran pẹlú àmi àyò kan sodo.

Senegal yóò kojú ẹgbẹ́ agbabọọlu England ní Ìpele jíjá ní kíákíá, nígbà tí England yóò kojú USA.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button