Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé-iṣẹ́ Ajílè ọ̀gbìn Dangote ṣe Ìgbéláruge Ìdàgbàsókè iṣẹ́-ọ̀gbìn – Ẹgbẹ́

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 297

Ilé-iṣẹ́ ajílè  Dangote,gẹ́gẹ́ bí nǹkan tí Ọ̀gbẹ́ni Olúṣọlá Obadimú, Olùdarí Gbogbogboò  Ẹgbẹ́ Aṣojú Àwọn Ilé-iṣẹ́ Ìṣòwò, Ilé-iṣẹ́ tó ń ṣẹ̀dá,àlùmọ́nì inú ilẹ̀, àti iṣẹ́-ọ̀gbìn (NACCIMA), yóò ṣe ìgbéláruge ìdàgbàsókè iṣẹ́ ọ̀gbìn  orílẹ̀-èdè.

Ọga NACCIMA sọ eyi ni ọjọ Abamẹta ni Ilu Eko nigba to n jabọ lori abẹwo si ile-iṣẹ Ajile Dangote ni agbegbe Ibẹju Lekki.

O sọ pe ipilẹṣẹ naa yoo ṣe ipese aabo ounjẹ ati pe yoo ṣe agbekalẹ ọpọlọpọ ipese iṣẹ fun awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria ati awọn ọmọ Afirika miiran.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button