Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpàtẹ ọjà káríayé ẹlẹ́ẹ̀kẹtà-dínlógún bẹ̀r̀ẹ

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 400

Ìpàtẹ ọjàẹlẹ́ẹ̀kẹtàdín-lógún ti Oníṣòwò Àgbáyé nílùú Abuja tí ilé iṣẹ́ títà rírà àti Ilé-iṣẹ́ okòwò Àbújá (ACCI) ti bẹ̀rẹ̀, ní òpin ọ̀sẹ̀, ní pápá ìtajà oníṣòwò tí ó wà ní olú-ìlú.

Gbólóhùn kan ti oṣisẹ ACCI fun eto ibaraẹnisọrọ/ọgbọn, Olayemi John-Mensah,gbe jade ni ilu Abuja sọ pe ipatẹ ọja naa, ti o ni  akori, “Ṣiṣẹda ọja ti wọn ti ṣetan lati okeere Nipasẹ ẹrọ ayelujara SME ,” yoo gba awọn ẹẹdẹgbẹta olutaja, awọn ọja ẹgbẹrun mẹwa, ati Alejo ti o ju ọgọrun ẹgbẹrun lọ.

O sọ pe, “Ni ọjọ akọkọ, ọpọlọpọ awọn olutaja lati inu ati okeere Naijiria ti wa ni ilẹ pẹlu awọn ọja ti o joju nigbese  ati pe awọn alejo ti bẹrẹ si ni wa ra wo ọja naa’.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button