A tún Olùdarí Egbé òsèlú Àlátakò Orílẹ̀-èdè Tunisia Ṣílẹ̀ Lẹ́yìn òpòlopò Íwádìí Àti Ti Ìfọ̀rọ̀wéró
Olùdarí Egbé òsèlú Àlátakò orílẹ̀-èdè Tunisia gba ìtùsílẹ́ lẹhin ọpọlọpọ ifọ́rọ́werọ́ àti ìbéèrè láti ọ dọ àwọn tó n ṣàkoso ìwà ìbàjẹ́, ni ọjọ́ ìsẹgun,lori èsún ìkówó pàmò, àti ìwà ìbàjẹ́ .
Rachad Ghannouchi,eni okanlelogorin, Olùdarí ẹgbẹ́ òsèlú ẹsìn isilamu,ni wọ́ gbà láti padà sílé, lẹyìn wákàtí mésàn gbígbọ́ láti ẹnu rẹ̀
Leave a Reply