Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Fáyẹmí Yóò Sí Àwọn Ọ̀nà Titun Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

0 275

 

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkìtì, Káyọ̀dé Fáyẹmí yóò sí àkànse àwon ọ̀nà tuntun ní ọjọ́ ọjọ́bọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Kọmísọ́nà fún ìròyìn, àsà àti ìgbafẹ́, Dókítà Wàsíù Ọlátúbọ̀sún ló sọ èyí ní ọjọ́ ajé.

Ó sọ wípé àwọn ọ̀nà tí wọn yóò sí nìwọ̀nyih: Ìdí Àpé-Odogbó Barack Road(Kìlómítà méje ó lé díẹ̀) àti General Gas Flyover, tí Gómìnà Sèyí Mákindé sẹ̀sẹ̀ pari rẹ̀.

Ọlátúbọ̀sún jẹ́ kó di mímọ̀ pé ayẹyẹ náà yóò wáyé ní Isabatudeen Girls Grammar School, Oríta Basọ̀run, Ìbàdàn.

Ó sọ síwájú pé, ọ̀nà tuntun sísí jẹ́ ọ̀kan lára ohun gbógì mẹ́rin tí Gómìnà Sèyí Mákindé ti sètò sílẹ̀ fún ìdàgbàsókè Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

 

 

Temitope Obisesan

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button