Take a fresh look at your lifestyle.

Eid-El-Kabir: Ẹjẹ́ kí á fi ìfẹ́ bárawa lò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà: Ààrẹ Buhari

0 477

Ààrẹ Muhammadu Buhari késí àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti jẹ́kí ànfàní orílẹ̀-èdè kó jẹwọ́n lógún, kósì lékè àwọn ìwà ìmọtara-ẹni-nìkan.

Nínú ọ̀rọ̀ Eid-el Kabir rẹẹ̀ sí àwọn Mùsùlùmí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti àwọn ará ìlú mìíràn, Ààrẹ Buhari sọ pé “tí a bá ń wu  àwọn ẹ̀kọ́ tí àwọn ẹ̀sìn wa ń kọ́wa níwà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ibi tí ó ń sẹlẹ̀ ní àwùjọ wa ni à báá ti yanjú.”

 

Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button