Ààrẹ Muhammadu Bùhárí ń darí ìpàdé ọlọ́sẹ̀ẹ̀sẹ̀ Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ Ìjọba Àpapọ̀ ní gbọ̀ngàn ilé ìgbìmọ̀ ọfiisi Ààrẹ,ni Villa, Abuja.
![]()
Awọn ti o wa nibi ipade naa ni: Igbakeji Aarẹ Yẹmi Ọṣinbajo; Akọwe fun ijọba apapọ, Boss Mustapha ti Akọwe agba ni ọfiisi rẹ, Habiba Lawal,ṣoju, Olori awọn oṣisẹ ijọba apapọ , Dokita Fọlaṣade Yẹmi-Ẹsan ati Olori Awọn oṣiṣẹ fun Aarẹ, Ọjọgbọn Ibrahim Gambari .
![]()
![]()
Awọn minisita to tun wa nibẹ pẹlu ni; Minisita fun eto iroyin ati asa, Lai Mohammed, Adajọ agba and Minisita fun eto idajọ, Abubakar Malami, Inawo, Zainab Ahmed ati Iṣẹ ati Ibugbe, Babatunde Fashọla.
![]()
Awọn miiran tun ni minisita Iṣẹ ati Igbanisiṣẹ, Dokita Chris Ngige, Agbara, Abubakar Aliyu, kata kara,ile-iṣẹ ati Idoko-wo, Niyi Adebayo, Olu-ilu, Mohammed Bello ati Minisita Ipinlẹ fun ilera, Mamora Ọlọrunnimbe.
Awọn minisita toku n kopa lati awọn ọfiisi wọn ni Abuja.
Alaye nigbamii……..
Leave a Reply