Take a fresh look at your lifestyle.

2023: olùdíje gómìnà PDP ní ìpínlẹ̀ Plateau Yan igbákejì obìnrin

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 220

ìpínlẹ̀ Plateau, Barr. Caleb Mutfwang, ti yan Ìyáàfin Josephine Piyo gẹ́gẹ́ bí igbákejì rẹ̀ fún ìdìbò gbogbogbòò ọdún 2023.

Piyo ẹni ti wọn ṣe afihan rẹ nibi ayẹyẹ  to waye ni ofiisi ẹgbẹ oṣelu PDP nipinlẹ Jos, olu ilu ipinlẹ naa, jẹ oloselu igberiko ati Alaga ijọba ibilẹ Riyom nigba kan ri nipinlẹ naa ati pe o ti figba kan je aṣofin tẹlẹ ni ile igbimọ aṣofin ipinlẹ naa.

Agbẹjọro Mutfwang sọ pe, yiyan Piyo yoo nipa lori ṣiṣoju  awọn eniyan

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button