Take a fresh look at your lifestyle.

Macron jáwé olúborí nínú ìdìbò ààrẹ Faransé

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 426

Ààrẹ Faransé lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, Emmanuel Macron ti ní ìdá méjìdín-lọ́gọ́ta-ó-lé-díẹ̀ ìbò nínú ìdìbò ààrẹ,tí  ó sì ṣẹ́gun olùdíje ti National Rally  Marine, Le Pen, tí òhun ní ìbò ìdá oókànlé-lógójì-ó-lé-díẹ̀.

Gẹgẹ bi awọn abajade lati Ile-iṣẹ iṣiroorilẹ-ede Faranse ti o ṣafihan rẹ ni ọjọ aje,abajade naa fẹẹ dabi ibo Macron ni ọdun 2017, nigbati o jawe olubori pẹlu ida ookanle-lọgọta,ti Le Pen si ni ibo ida mẹtale-lọgbọn-o-le-diẹ ni ọdun marun sẹhin.

Ida mejidin-lọgbọn ti o lodi si ida mẹẹdọgbọn ni ko dibo ni ọdun 2017, ti o jẹ ida ti o kere julọ ninu itan  idibo Aarẹ Faranse gbogboogbo lati ọdun 1969.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button