Nínú ìpàdé tí ó wáyé ní ìlú Abuja, olóyè kàbìtì kan nínú ẹgbẹ́ òsèlú, All Progressives Congress, APC, Ọ̀gbẹ́ni Bola Ahmed Tinubu ti fi ìpinnu rẹ̀ hàn fún àwọn gómìnà ẹgbẹ́ náà láti díje fún ipò ààrẹ.
Awọn gomina APC mejila ni o wa ni ikalẹ nibi ipade naa. Eyi si waye lẹhin ti igbakeji Aare Naijiria, Ojogbon Yemi Osinbajo ni ipade pẹlu awọn Gomina kanna lati sọ ipinnu rẹ ni gbangba lati dije fun Aare.
Leave a Reply