Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì Ààrẹ Ọ̀sínbàjò darapọ̀ mọ́ Ìdíje Ààrẹ ọdún 2023

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 377

Igbákejì Ààre Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò ti kéde ìpinnu rẹ̀ láti díje fún ipò Ààrẹ ní ọdún 2023.

Ọjọgbọn Ọsinbajo ṣe alaye yi  ni owurọ Ọjọ aje ninu ifiranšẹ fidio ti o gbasilẹ lori awọn amohunmaworan orilẹ-ede.

Igbakeji aarẹ sọ pe ẹkọ ti oun ti ni lati ọdun meje sẹyin ti o ti n ṣiṣẹ pẹlu Aarẹ Muhammadu Buhari ti mu oun ni iriri lati sin Naijiria gẹgẹ bi aarẹ.

Orisiirisii awọn ipe ti wa lati beere lọwọ igbakeji aarẹ lati kede erongba rẹ lati dije fun Ọfiisi aarẹ.

Ni alẹ ọjọ Aiku, o ṣe ipade pẹlu awọn gomina  All Progessives Congress, APC, ni ibugbe rẹ,ni Akinọla Aguda ni Villa, Abuja.

Ikede rẹ ni ọjọ aje fi erongba rẹ han fun ọdun ti n bọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button