Take a fresh look at your lifestyle.

Wizkid, Davido gbajúgbajà akọrin

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 409

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Davido àti Wizkid yàtọ̀ síra, wọ́n ní àwọn ẹ̀yà tí ó jọra.

Awọn mejeeji jẹ gbajugbaja akọrin ti wọn si gbe Afrobeat larugẹ debi wipe gbogbo aye  mọ ka.

Ipa orin alailẹgbẹ wọn tun fa idije nla laarin wọn bi wọn ṣe fi awọn nnkankan jọra wọn.Bi awọn mejeeji ti ṣe jẹ gbajugbaja olorin Afrobeat, wọn tun ti jọ ṣaṣeyọri to lami ninu orin kikọ.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button