Ìpele àkọ́bẹ̀rẹ̀ ìbò Gómìnà:Ẹgbẹ́ òṣèlú SDP tako èsì ìpínlẹ̀-Ọ̀ṣun
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Ẹgbẹ́ òṣèlú Social Democratic Party (SDP) ti tako ọ̀rọ̀ tó ń lọ káàkiri lórí ẹ̀rọ ayélujára lórí àbájáde ìdìbò àkọ́kọ́ gómìnà Ìpínlẹ̀ náà.
Alaga igbimọ idibo gomina ipinlẹ Ọsun, Ọgbẹni Joseph Abu, sọ pe awọn ti fi esi naa ranṣẹ si Igbimọ oṣiṣẹ apapọ ti SDP.
Ọgbẹni Abu fi kun un pe, wọn ko kede esi idibo alakọkọ ni ibi ti idibo alakọbẹrẹ ti waye. “Igbimọ naa ṣe idibo ọhun ti ẹgbẹ Igbimọ apapọ oṣiṣẹ ṣeto pẹlu irọwọ irọsẹ.Sugbọn wọn ko le kede Abajade ni gbagede naa nitori ijakadi awọn eniyan ti ko gba iwe-aṣẹ ati awọn ti kii ṣe ọmọ ẹgbẹ SDP.”
Leave a Reply