Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ṣàlàyé pé ìṣẹ̀lẹ̀ tó wáyé láìpẹ́ yìí kìí ṣe ogun bẹ́ẹ̀ni kìí sìí ṣe ìjà.
Oludari Agba fun igbimọ aala lorilẹ-ede lapapọ, Awọnlẹ Adamu Adaji,ṣalaye ni Abuja nibi apero kan lori awọn igbesẹ ti Igbimọ naa gbe laipẹ.
O sọ pe iroyin ti awọn ile-iroyin kan fi sita nipa bo ṣe n lọ laarin awọn ologun aabo orilẹ-ede Kamẹruun ati awọn ọmọ abinibi agbegbe Kwaja ati ilẹ-oko wọn ko ri bẹẹ rara,Awọnlẹ Adaji sọ pe,ko si nkan to jọ ija tabi ogun laarin wọn ti awọn orilẹ-ede mejeeji si jẹ aladugbo pelu ibaṣepọ to danmọran.
Leave a Reply