Take a fresh look at your lifestyle.

Aparo Kan O Ga Ju Ọkan; Ikọ Chelsea Duro Digbin Ti Ikọ Liverpool Ninu Ifẹsẹwọnsẹ Ọjọ Aiku

0 285

Bo tilẹ jẹ pe atamatase ikọ Chelsea, Romelu Lukakau ko si lori papa, wọn ko gbẹyin rara pẹlu bi wọn se fakọ yọ ninu ifẹsẹwọns plu ikọ Liverpool.

Sadio Mane lo kọkọ gba bọọlu wọle fun ikọ Liverpool, ti Mohammed Salah si gba lẹẹkji wọle. Leyi ba ru ikọ Chelsea ninu, ni Mateo Kovavic si da ọkan pada. Laipe jọjọ naa ni Christian Pulisic da lẹẹkji pada.  

Ikọ mejeeji lo gbiyanju lati mori bọ ninu ifẹsẹwọns naa, sugbon aparo kan ko ju ọkan lọ laarin ikọ mejeeji. Ọmi ni ifẹsẹwọns naa pari si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button