Ọ̀gá àgbà fún àwọn ọmọ ogun òfurufú (CAS), Air Marshal Ọládayọ̀ Àmàó ti rọ àwọn ọmọ-ogun Operation GAMA AIKI (OPGA) àti àwọn òṣìṣẹ́ 013 Quick Response Force (013 QRF), Minna, Ìpínlẹ̀ Niger láti ṣe iṣẹ́ wọn lásìkò iṣẹ́ àti tẹ̀síwájú láti jà fitafita títí di ìgbà tí àwọn oníjàgídíjàgan, àwọn adigunjalè àti àwọn ọ̀daràn mííràn yóò di ohun ìgbàgbé pátápátá, tí àlààfíà yóò sì tún fi padà sí Ìpínlẹ̀ àti gbogbo àwọn ẹ̀yà míràn lórílẹ̀-èdè.
Air Marshal Amao pe ipe yii lakoko ayẹyẹ Keresimesi pẹlu awọn ọmọ ogun Air Component ti OPGA ni Minna.
Igbakeji Oludari Awọn iṣẹ, Ile-iṣẹ NAF, Air Commodore Sunday Aneke, ti o ṣoju CAS, ṣe akiyesi pe apejọ naa tun pese anfani fun NAF lati ranti akitiyan awọn ọmọ ogun ti wọn ti jẹpe ọlọrun nidi iṣẹ fun orilẹ-ede.
Leave a Reply