Ìjàǹbá Iná Àbújá: Mínísítà fún ọmọnìyàn kẹ́dùn pẹ̀lú àwọn olùfaragbá
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Mínísítà fún ètò ọmọnìyàn, ètò àjálù àti ìdàgbàsókè àwùjọ, Sadiya Umar Farouq ti kẹ́dùn lórí ìpàdánù ọjà àti dúkìá tí ó tó bílíọ̀nù owó dọ́là Náírà, nínú ìṣẹ̀lẹ̀ iná tó wáyé ní ilé ìtajà gbajúgbajà, Next Cash and Carry, ní ìlú Àbújá.
Minisita naa bẹnu atẹ lu bi ajalu ina ni orilẹ-ede naa ṣe n waye lera ,o si rọ awọn eniyan ṣọra ati lati yago fun awọn iṣẹlẹ iwaju.
Iṣẹlẹ ti o waye ni ọjọ bọkisin naa ṣe Umar Farouq laanu pupọ ti paṣẹ fun Ile-iṣẹ Itọju Pajawiri Orilẹ-ede, NEMA, lati ṣe gbogbo iranlọwọ ti wọn ba le ṣe fun wọn ni ọjọ ijanba ina naa.
Leave a Reply