Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà Pín Owó tó tó Ọgọrun Bilionu Naira Fún Ìdásílẹ̀ Isẹ́

0 302

Ìjọba Nàìjíríà ti kéde pé òun ti pín ọgọ́rùn-ún bílíọ̀nù náírà láti fi dá iṣẹ́ sílẹ̀ fún àwọn ọ̀dọ́ àti láti kojú àìríṣẹ́ṣe tó ń gbòòrò sí i ní Nàìjíríà.

Eyi jade ninu atejade kan lati ọwọ Minisita fun iṣẹ, Ọgbẹni Festus Keyamo, SAN, ni ọjọ Aiku ni ilu Abuja.

Minisita naa fi kun pe ipinfunni ti ọgọrun bilionu naira naa ni a ṣe nipasẹ ile ifowopamọsi idagbasoke ti Nigeria lati ọdun 201 lati le ro awọn ile-iṣẹ kee-kee-kee lagbara (MSMEs); pẹlu ero lati pese iṣẹ fun awọn alainiṣẹ ti orilẹ-ede naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button