Take a fresh look at your lifestyle.

 Ìgbìmọ̀  ṣe ìfilọ́lẹ̀ ibùdó tuntun fún àwọn asásálà   ní ìpínlẹ̀ Nasarawa

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 435

 

 

Ní ìbámu pẹ̀lú àṣẹ  láti pèsè ààbò àti ìrànlọ́wọ́ fún ènìyàn nípa pípèsé ìtùnú fún àwọn  tí  àjálù kàn, Ìgbìmọ̀  Orílẹ̀-èdè fún Àwọn Asásálà, Àwọn tì wọ́n ṣí láti ibìkan sí òmíràn àti Àwọn ènìyàn tí wọ́n fi ipá lé kúró ní ibùgbé wọn, ti  ṣe ìpìlẹ̀ ìfilọ́lẹ̀ fún iṣẹ́ àkànṣe ibùgbé tuntun ní  Ìpínlẹ̀ Nasarawa.

Ni ṣiṣe ipilẹ ifilọlẹ yii  ni Keffi, Komisona apapọ, Imaan Sulaiman Ibrahim, ṣe alaye pe iṣẹ akanṣe naa  lero lati koju ipeni nija pataki lori ọrọ ibugbe fun  Awọn eniyan ti ọrọ kan, paapaa julọ, awọn IDPs.

Gẹgẹ bi Kọmiṣiọna apapọ naa ṣe sọ,iṣẹ akanṣe naa yoo ṣe atunṣe,atunto ati titẹdo awọn ti ọrọ ọhun kan ni awujọ.

.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button