Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà nílò ọ̀kẹ́ àìmọye dọ́là fún ìdàgbàsókè amáyédẹrùn

0 356

Ààrẹ Muhammadu Buhari,ti ni orílẹ̀ èdè  Nàìjíríà yóò nílò ọ̀kẹ́ àìmọye owó ilẹ̀ òkèèrè tó lé ni tiriọnu dọla fún ètò ìdàgbàsókè ohun amáyédẹruǹ.

Ààrẹ Muhammadu Buhari sọrọ yii lọ́jọ́ Ìsẹ́gun níbi ipade apero agbaye  COP 26 ní ìlú Glasgow.

Ààrẹ Buhari tún kéde pé ìjọba òun ti se gudu gudu meje , yaya mẹfa  lati mu eto idagbasoke ba ohun ameyedẹrun  lorilẹ ede Nàìjíríà.

Ààrẹ Buhari tun tẹsiwaju pe  awọn eto ti wọn ti gbe kalẹ yóò wulo lọpọlọpọ lati lee mu pupọ ọmọ orilẹ ede Naijiria kuro  ninu osi ,ki o to di ọdun 2023

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button