Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn ènìyàn mọ́kàndín-lọ́gọ́jọ míràn tún ti ní ààrùn covid

0 381

Àwọn ènìyàn mọ́kàndín-lọ́gọ́jọ míràn ló tún ti kó ààrùn covid jákèjádò orílẹ̀-èdè lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí.

Ajọ to n mojuto ajakalẹ aarun ni orilẹ-ede (NCDC) ni kede eyi nibi ifitonilẹti ojoojumọ rẹ.

Awọn eniyan yii jẹyọ ni awọn ipinlẹ mejila.Olu-ilu ti o ko ipa to pọju nibẹ ni (ookan-le-laadọrin) ,Lagos (ogun),Imo (mẹtadin-logun) ,Rivers (mẹẹdogun), Cross River( mẹsan-an), Kano (meje ),Ondo (meje), Plateau (mẹrin ),Ekiti (mẹta ), Niger (mẹta ) ,Delta (meji ) ,Bauchi (ẹyọkan).

Bayii, awọn eniyan ọ̀kẹ́ mẹ̀wá abo o din ni ẹ̀fà din ni ọ́ta lo ti ni aarun ọhun ti mèjì-din-ni-ojì le ni ẹgbẹ́ẹ̀rinlá eniyan si ti jẹpe oluwa. Jakejado orilẹ-ede.

Nibayi, Dokita Ifedayo Adetifa ti  bẹrẹ iṣẹ ni NCDC gẹgẹ bi Oludari Gbogbogbo Tuntun.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button