Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

President Muhammadu Buhari

Kò Sí Orílẹ̀-èdè Tí o Leè Lékè Nípa Ìwà Àìní Òdodo Àti Ẹ̀sẹ̀ – Ìgbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo

Ìsìn Ìbúra sípò Ààrẹ Àti Igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà ọdun 2023 wáyé ní ilé Ìjọsìn ni ecumenical Centre nílùú Abuja ní ọjọ́ kejidinlọgbọn, oṣù karùn-ún, ọdun 2023 Àwọn ènìyàn pàtàkì  lo wa ni bi ìsìn yii, Lára àwọn ènìyàn pàtàkì tí ó…

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Ọ̀rọ̀ – Ọ̀rọ̀ ìdágbére Láti Ẹnu Ààrẹ Muhammadu Buhari, Ààrẹ Orílẹ̀-Èdè…

Ẹ̀yin ènìyàn mi lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, àti àwọn tó ń gbé káàkiri àgbáyé. Mò ń bá a yín sọ̀rọ lóní, èyi tó jẹ́ iṣẹ́ mi tí ó gbẹ̀yìn gẹ́gẹ́ bi Ààrẹ Ìjọba tiwa-n-tiwa tí a yàn sípò gẹgẹ bi ààrẹ orilẹ-ede…

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Ghana Ní Alága Ìfilọ́lẹ̀ Àwọn Ìwé Lórí Ààrẹ Nàìjíríà

Ààrẹ Nana Akufo-Addo tí Orílẹ̀-èdè Ghana ní á n'ìrètí látí ṣé Alága ìgbéjáde àtí ìfilọ́lẹ̀ àwọn ìwé túntún méjì kàn lórí àwọn ipá tí Aare Muhammadu Buhari kó lórí ìdàgbàsókè Orílẹ̀-èdè ní ọjọ́ Ẹtì, ọjọ kokandinlogun 19 Oṣù Kàrún ùn, ní…

Ààrẹ Buhari Ṣí Àwọn Ìṣẹ́ Àkànṣe TETFUND Ẹlẹgbẹ-gbẹ́ Bílíọ̀nù Náírà Ní Makurdi

Ààrẹ Muhammadu Buhari ní Ọjọ́bọ̀, tí ṣí àwọn iṣẹ́ àkànṣe mẹ́fà nípasẹ̀ Àjọ ìnáwó Ilé-ẹ̀kọ́ gíga (Tertiary Education Trust Fund TETFUND) ní ilé-ìwé gíga tí Benue State University, Makurdi, ní Àárín gbùngbùn Àríwá, Nàìjíríà. Ààrẹ Buhari…

Ẹ́ Fí Àyè Gbá Àwọn Aṣojú-Owó Látí Wá Ojútùú Sí Owó Tuntun – Ìgbákejì Ààrẹ Pàrọ̀wá Fún Àwọn…

Ọnà sí ìṣòro tí àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń kojú lórí owó tuntun ní kí Bánkì gbogbogbò orílẹ̀-èdè yìí (Central Bank of Nigeria CBN) àtí àwọn Bánkì Ìṣòwò (Commercial Banks) fí ayé púpọ̀ díẹ̀ síì gbà àwọn aṣojú owó àti FinTech látí kojú…
button