NIDCOM Dún-nú Pẹ̀lú Ọmọbìnrin Àkọkọ́ Tó Gbá Akọgún Nílùú Amẹ́ríkà
Olórí Ilé-iṣẹ́ tó ń rí sí ètò àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lókèèrè (Nigerians in Diaspora Commission NiDCOM), Dókítà Abike Dabiri-Erewa, tí kí Amanda Azubuike lórí ìgbéga rẹ̀ sí 'Brigadier General' nínú ọmọ ogún Orílẹ̀-ẹ̀dẹ̀ Amẹ́ríkà.
…