Ìbò Dídì Bẹ̀rẹ̀ Pẹrẹu Ní Ìlú Kano, Tí Àwọn Ọmọ Ológun Náà Sí Dúró Wámúwámú
Ìbò dídì ti Gómìnà àti Ilé Aṣòfin ti bẹ̀rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Kano àti gbogbo àgbègbè rẹ̀ pẹ̀lú àdúrótì àwọn ọmọ ológun.
Àjọ INEC náà sì ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ wọn ní pẹrẹu.
Bí ìbò dídì ṣe ń lọ ní ikọ̀ àwọn ẹ̀sọ́ ń káàkiri pẹ̀lú ọkọ̀…