Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

#ìdìbò_Gómìnà_Ọdùn_2023

Àwọn Ènìyàn Ìlú Calabar Gbóríyìn Fún Àjọ Elétò Ìdìbò Fún Ìgbáradì Tí Ó…

Àwọn ará ìlú Calabar, ti àgbègbè IBB àti Atimbo ní Ìpínlẹ̀ Cross River ti gbé òsùbà fún Àjọ Elétò Ìdìbò fún ètò tí ó péye àti ìpèsè oun èlò fún ìdìbò lásìkò tí ó yẹ, fún ìdìbò Gómìnà àti…

A ti sèkìlọ̀ fún àwọn Yorùbá ní ìpínlẹ̀ Jigawa láti yẹra fún ìwà jàndùkú lásìkò ìdìbò – Ọba…

Ọ̀ba àwọn Yorùbá ní ìlú Dutse to jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ Jigawa ọba Murtala Muhammad Mas'ud,Sarkin Yorùbáwá Dutse emirate ti ni kó tó di ọjọ́ ìbò ni àwọn ti se ìpàdé lọba-lọba láti sèkìlọ̀ fún gbogbo àwọn ọmọ Yorùbá tó ń gbé ni ìpínlẹ̀ Jigawa…

Ètò Ìdìbò Gómìnà Àti Aṣoju Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ti Bẹ̀rẹ̀ Ní Ìpínlẹ̀ Abia.

Ni agbegbe Umuahia ni ìpínlẹ̀ Abia níbi tí àwọn àjọ elẹ́tò ìdìbò kalẹ si fún ìdìbò yíyan Gómìnà àti asojú ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ ní àyẹ̀wò ìdìbò ti bẹ̀rẹ̀. Ilé Akéde Nàíjíríà Voice of Nigeria ṣe ìbẹ̀wò sí àwọn agbègbè…

Àwọn Àgbàgbà Ẹkùn Ìwọ Òòrùn Rọ Àjọ Elẹ́tò Ìdìbò Láti Pèsè Ààbò Tó Péye Ní Ọjọ́ Àbámẹ́ta.

Ẹgbẹ́ àwọn àgbà ni iwọ òòrun Áfíríkà ti rọ àjọ elẹ́tò ìdìbò, àwọn òṣìṣẹ́ aláàbò àti àwọn tọrọ kan láti rí wí pé ìdìbò ọjọ́ àbámẹ́ta lọ ni irọwọ ati irọsẹ Ẹgbẹ́ WAEF sọ èyí ni ìlú Abuja nínú ìwé àtẹjáde ti alaga ẹgbẹ́ náà, àti…
button