Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Pé Fún Ìsọkan Orílẹ̀-èdè
Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Godswill Akpabio tí tún pé fún ìsọkan orílẹ̀-èdè, Ó ṣé àpèjúwe onírúurú ẹ̀yà, àṣà àtí ẹsin gẹ́gẹ́ bí òun àmúse-àgbàrá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Sẹnatọ̀ Akpabio sọ̀rọ̀ yí làkókò tó ń bá àwọn ọmọ ijọ 'Presbyterian…