Orílẹ̀-èdè Somalia ń fẹ́ ki àjọ ọmọ ogun apẹ̀tùsáwọ̀ AU àlàáfíà má tètè kò ikọ̀ ọmọ ogun kúrò ní orílẹ̀-èdè wọn. Wọ́n sọ fún Àjọ UN láti ní sùúrù fún osù mẹ́ta kí abala tó kàn àjọ ikọ̀ ọmọ ogun African Union Transition Mission in Somalia (ATMIS) kí wọ́n tó lọ.
Àpapọ̀ ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ikọ̀ ọmọ ogun oni ọ̀kọ̀ọ̀kan ẹgbẹ̀rún mẹ́tàdínlógún ọmọ ogun tó lè koko ní wọ́n yẹ ki wọn lọ ní òpin oṣù, ni àbàlá èkejì ìkókúrò.
Ṣùgbọ́n, ìjọba Somalia sì gbógun ti ikọ̀ ọmọ ogun al-Shabab, wọ́n sì ń ní ìfàsẹ́yìn.
Ìkókúrò omo ogun díẹ̀díẹ̀ ló ti bẹ̀rẹ̀ ní oṣù kẹfà.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply