Kókó Ayẹyẹ ti ẹlẹ́ẹ̀kẹ̀wá irú rẹ̀ – 10th summit of the Organization of African, Caribbean and Pacific States, parí ti Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Angola tún forile ilu Washington fún ìpàdé miiran.
Igbákejì ààrẹ aare ìlú Slovenia náà wà níbí ìpàdé náà ní ìlú Luanda.
Nígbà àkọ́kọ́ tí Tanja Fajon’s kọ́kọ́ lọ sí ìlú Angola, olórí ti ẹ̀ka òṣèlú ti ìlú Slovenia sọ̀rọ̀ nípa àjọṣepọ̀ wọn pẹlú ilẹ̀ adúláwọ̀.
Kò tí di mímọ̀ bóyá wọn yóò rí ojú rere ti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láti ọ̀dọ̀ àjọ ọmọ ẹgbẹ́ ti Organization of African, Caribbean and Pacific States náà gbà.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply