Take a fresh look at your lifestyle.

Ìlúmọ̀ọ́ká Ọmọbíbí Ilẹ̀ Amẹ́ríkà Bí Ọmọ Ẹlẹ́ẹ̀kejì

0 222

Ìlúmọ̀ọ́ká ọmọbíbí ilẹ̀ Amẹrika, Megham Trainor ti kéde àmójúbà ọmọ tuntun jòjòló ẹlẹ́ẹ̀kejì lórí ẹ̀rọ ayélujára . Ó dáwọ̀ọ́ ìdùnnú pẹ̀lú ọkọ rẹ̀ látàrí bí wọ́n se bí ọmọ tuntun sáyé ní ọjọ́ kìníí osù keje, ọdún 2023.

 

Ó fi àwòran fọ́tò òun àti ọmọ tuntun náà hàn, èyí tí ojú rẹ̀ kún fún ìdùnnú àti ayọ̀. Ó dúpọ́ lọ́wọ́ àwọn akọ́ṣẹ́-mọṣẹ́ Dókítà elétò ìlera fún iṣẹ́ ribi-ribi tí wọ́n se àti ìtọ́jú tí ó péye.

 

Tí a kò bá gbàgbé, àwọn tọkọ-taya naa bí àkọ́bí ọmọ, Riley, ni ọjọ kẹjọ, osù kejì, ọdun 2021. Ó dájú pé ọmọkùnrin ẹlẹẹkeji ni Ọlọ́run fi ta wọ́n lọ́rẹ báyìí.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button