Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ekiti Tẹlẹ Gbóríyìn Fún Àwọn Ìgbésẹ̀ Ààrẹ Tinubu

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 400

Gómìnà nígbà kàn rí ní ìpínlẹ̀ Ekiti, Ayodele Fayose tí gbóríyìn fún àwọn ìgbésẹ̀ ìgboyà tí Ààrẹ Bola Tinubu ń gbé báyìí.

Nitorinà, Ó ń kési gbogbo ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà látí ṣé àtìlẹ́yìn fún Ààrẹ, nítori wípé “kó lé dá ṣé.”

Fayose ṣé ìmọràn náà ní ìlú Abuja ní Ọjọ́bọ̀ làkókò tó n bá àwọn òníròyìn Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ sọrọ, lẹyìn tó ṣé àbẹwò ìṣọ̀kan sí Olori Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button