Take a fresh look at your lifestyle.

Ikọ Agbabọọlu Man City Fe Gbemi Ni Ọdun 2020

0 568

Atamatase ikọ Chelsea, Romelu Lukaku fọhun. O wipe, ikọ agbabọọlu Manchester City ransẹ si ohun ni ọdun 2020 lati gbe ohun wa si ikọ wọn sugbọn, nkan o sara re o. Ohun fi ọbe eyin jẹ wọn nisu.

Lukaku ṣe ifihan yii nibi ifọrọwanilẹnuwo pẹlu Sky Italia.

O fi idi rẹ mulẹ pe owo ti ikọ Man City gbe wa pọ lọpọ ju  ti ẹgbẹ agbabọọlu Chelsea lọ sugbọn ohun kọ wọn silẹ nitori pe ikọ Chelsea ni o wu ohun lati pada si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button