Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Onítẹ̀síwájú Dá Ìwọ́ Ìdùnnú pẹ̀lú Inuwa Yahaya

0 290

Àkójọpọ̀ àwọn Gómìnà onítẹ̀síwájú ti dunnú pẹ̀lú gómìnà Muhammadu Inuwa yahaya ti ìpínlẹ̀ Gombe níbi ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọdún mọ́kànlélọ́gọ́tá rẹ̀.

 

Àjọ náà kọ́wọ̀ rín pẹ̀lú àwọn ọmọ ìpínlẹ̀ Gombe àti gbogbo ọmọ Nàìjíríà láti kí gómìnà kú oríire. Wọ́n gbé òsùbà fún -un lórí síse àkóso àti ìlàkàkà rẹ̀ fún ìsọ̀kan orílẹ̀ èdè wa.

 

Wọ́n se àfirinlẹ̀ síse àkóso rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó ti mú ìlọsíwájú bá ìpínlẹ̀ Gombe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button