O jú igbá (200) ilé àwọn olùgbé ní àgbègbè Nuwalege, lẹ́bá Òpópó-ọ̀nà Pápá-kọ̀ Òfurufú ní Abuja tí wọ́n tí wó látí ṣé ìgbà láàyè fún Ilé-iṣẹ́ ológun òfurufú (Nigeria Air Force NAF).
Ẹ̀ka (FCT Department and Development Control) tí Ìṣàkóso àti Ìdàgbàsókè tó ṣiṣẹ́ yí lópin ọsẹ sọ pé ó ṣé dàndàn látí fẹ́ ayé fún ọkọ̀ Òfurufú Ààrẹ.
Olùdarí tí Ẹka náà, Mukhtar Galadima, sọ fún àwọn oníròyìn lẹ́yin ìṣẹ́ náà, pé Olórí Òṣìṣẹ́ òfurufú tí bá Alákóso tí Abuja ní Oṣù Kẹwàá ọdún 2023 lórí àwọn ìpinnu wọ́n látí wó díẹ̀ nínú àwọn ilé lórí ilẹ̀ náà.
O ní Mínísítà FCT, Nyesom Wike, sọ wípé ojúṣe àwọn alákóso ìjọba Abùjá ní látí wó àwọn ilé náà.