Enugu:Àwọn jàǹdùkú dáná sun olú ilé-iṣẹ́ àjọ t́i ó ńṣàmójútó ètò ìdìbò
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Ile iṣẹ ajọ to nmojuto eto idibo[INEC]ti ke gbajari pe awọn janduku kan ti dana sun ọkọ Hilux mẹfa ni olu ile-iṣẹ wọn ni ọjọ aiku.
Kọmiṣọna apapọ ati alaga , oluṣakoso ati Igbimọ idanilẹkọ awọn oludibo[INEC],agbẹjọro Festus Okoye fi idi ẹ mulẹ ninu atẹjade kan ti o jade ni ọjọ aje.
Gẹgẹbi Igbimọ naa, Komisona idibo ti INEC (REC) fun Ipinle Enugu, Emeka Ononamadu, ṣe ijabọ ikọlu naa si olu Ile-iṣẹ ọhun ni alẹ ọjọ aiku ,oṣu Karun,ọjọ kẹrin din-logun,ọdun 2021.
Leave a Reply