Àkójọpọ̀ àwọn alákóso tí àwọn ilé-ìwé Gírámà ní Nàìjíríà, [All Nigerian Confederation of Principals of Secondary School, ANCOPSS], sọ pé àwọn yóò tẹ̀síwájú láti ṣé àtìlẹ́yìn àwọn iṣẹ́ alamọdaju àti gbá àsìá ẹgbẹ́ náà duro.
Èyí ní Ààrẹ ẹgbẹ́ ANCOPSS, Alhaji Bello Gupa sọ dì mímọ lákókó ìpàdé ìgbìmọ̀ náà tó wáyé ní Model Girls’ Junior Secondary School, AMAC Estate ní Abuja, olú-ìlú Nàìjíríà.
Ààrẹ náà sọ pé ẹgbẹ́ àwọn ọgá àgbà àwọn ilé-ìwé gírámà náà ní ojúṣe pàtàkì kàn láti ríi dájú pé òfin àti ìlànà duroṣinṣin gẹ́gẹ́ bí àwọn tó kú ní àgbáyé.
Ní ìparí ìpàdé náà ní ẹgbẹ́ náà fún àwọn ọmọ ilé-ìwé náà ní Sikolashipu FCT 2022 ní Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ilé-ìwé náà.
Leave a Reply