Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÁRAYÀ
This is a category for sport news
Oshodi Fí Ìdùnnú Rẹ̀ Hàn Lórí Ìṣọ̀kan Ilẹ̀ Áfíríkà Nípasẹ̀ Tẹ́nìsì Orí Tábìlì
Bí ìdíje tẹ́nìsì orí tábìlì tilẹ̀ Áfríkà 2026 (ITTF Africa Cup 2026) ṣe bẹ̀rẹ̀, Ààrẹ Ẹgbẹ́ Tẹ́nìsì Orí Tábìlì ti Áfíríkà (ITTF Africa), Wahid Enitan Oshodi, ti yin ìdíje náà ní Libya gẹ́gẹ́ bí ìṣẹ̀lẹ̀ pàtàkì kan tó kọjá eré ìdárayá, tó ń…
Àjọ NSC Faramọ́ Ìgbàlejò Ìdíje Eré Gọ́ọ̀fù
Àjọ National Sports Commission (NSC), ti faramọ́ Igbalejo idije ere Gọ́ọ̀fù ti All Africa Challenge Trophy (AACT), ọdún 2026 fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti yóò wáyé ní
IBB International Golf and Country Club ní ìlú Abuja.
…
CAF Dá Olùkọ́ni Senegal Dúró Fún Rògbòdìyàn Ìdíje AFCON
CAF ti dá olùkọ́ni Senegal Pape Thiaw dúró fún ifẹsẹwọnsẹ márùn-ún, wọ́n sì tún bu owó ìtanràn ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́rùn-ún dọ́là ($100,000) fún lórí ìwà tó kù díẹ̀ kaato tó wú lẹ́yìn tó sọ fún àwọn agbábọ́ọ̀lú rẹ̀ pé kí wọ́n kúrò lórí pápá…
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Yóò Gbáradì Ni Scotland Fún Ìdíje Commonwealth– NSC
Àjọ National Sports Commission (NSC), ti sọ àsọdajú pe àwọn eléré ìdárayá Nàìjíríà yóò peju pésẹ̀ nibi igbaradi ọlọ́sẹ̀ mẹ́rin ni orílẹ̀-èdè Scotland latàri Ìdíje Kọ́mọ́wẹ́ẹ̀tì ọdún 2026 to n bọ̀.
Ọgá agba àjọ NSC,…
CAF Champions League: Power Dynamos Àti Rivers United Tá Ọmi
Ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ fún Rivers United láti ní àmì mẹ́ta lórí tábìlì nínú idije CAF Champions League láàrín ikọ náà ati power Dynamos, ni papa iṣere Levy Mwanawasa ní Ndola, Zambia lo wá sí òfo.
Rivers United ati Power Dynamos bẹrẹ pẹlu…
Manchester United fìdíẹ̀ múlẹ̀ pé Casemiro ti tẹ̀ síwájú gégẹ́ bíí òpin àdéhùn
Agbábọ́ọ́lù ipò ààrín fún Manchester United, Casemiro, yóò kúrò ní abala Premier League, tí sáà yí bá parí gẹ́gẹ́ bí òpin àdéhùn náà, ilé agbábọ́ọ́lù náà kéde.
Ọmọ ọdun mẹtale-lọgbọn naa le sun ọjọ naa…
’Rivers United’ Àti ‘Power Dynamos’ Tí Ṣetán Láti Kojú Ara Wọn Nínú Ìdíje…
Rivers United tí ṣetán fún ifẹsẹwọnsẹ pàtàkì tí ọjọ́ Àbámẹ́ta yìí, bí wọn yóò ṣé kojú ikọ̀ 'Power Dynamos FC' tí Zambia nínú ìdíje tí 'CAF Champions League'.
Ikọ̀ Rivers United tí gbéra lọ sí Ndola ni Zambia pẹ̀lú ìgboyà láti borí…
Osimhen, Lookman, Bassey Wà Lára Agbábọ́ọ̀lù Mọ́kànlá Ilẹ̀ Adúláwọ̀ Tó Dára Jùlọ Ti AFCON Ọdún 2025.
Àjọ Confederation of African Football (CAF), ti sísọ lójú eégún ní ojọ́ Ọjọ́rú agbábọ́ọ̀lù Mọ́kànlá Ilẹ̀ Adúláwọ̀ tó dára jùlọ ti AFCON Ọdún 2025 ti ikọ̀
Super Eagles orílẹ-èdè Nàìjíríà sì ní àwọn ògbóntàrigi akọni bíi
Victor…
Troost-Ekong Darapọ̀ Mọ́ Ẹgbẹ́ Qatar Al Ahli SC
Balógun Super Eagles ti Nàìjíríà tẹ́lẹ̀, William Troost-Ekong, tí buwọ́lù ìwé àdéhùn pẹ̀lú sí ẹgbẹ́ Qatar kán Al Ahli SC.
Troost-Ekong, ọmọ ọdún méjìlèlọ́gbọ̀n 32, agbábọ́ọ̀lù ẹyin kúrò nínú ẹgbẹ́ Saudi Al Kholood — níbi tó ti ń ṣé…