Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ

This is a category for politics news

Ààrẹ Tinubu Yan Gómìnà ìpínlẹ̀ Gombe Gẹ́gẹ́ Bí Aṣojú Ìrètí Tuntun Àti Akọ̀wé

Ààrẹ Bola Tinubu ti yan Gómìnà Ìpínlẹ̀ Gombe, Muhammadu Yahaya, gẹ́gẹ́ bí Aṣojú Ìrètí Tuntun àti Akọ̀wẹ́ fún Ìrànlọ́wọ́ Ẹgbẹ́, Ìbáṣepọ̀ àti Ìṣíṣẹ́. Ìyàn náà wà nínú lẹ́tà kan tí Ààrẹ fọwọ́ sí, tí ó pàṣẹ fún Gómìnà Yahaya láti gba àwọn…

Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC Ti Ìpínlẹ̀ Kano Wà Lẹ́yìn Ààrẹ Tinubu, Gómìnà Yusuf Fún Ìdìbò Ọdún 2027

Àwọn alenulọ́rọ̀ ẹgbẹ́ All Progressives Congress (APC) tí agbègbè Ariwa ìgbìmọ̀ aṣòfin ti ìlú Kano ti ṣe ìlérí láti kó ìtìlẹ́yìn ńlá fún Ààrẹ Bola Tinubu, Gómìnà Abba Yusuf àti Igbákejì Ààrẹ ti Ìgbìmọ̀ aṣòfin, Barau Jibrin, jọ…

Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC Osun Gba Àwọn Tó Sákúrò Ní Ègbé Òṣèlú PDP Mọ́ra, Fi Òùntẹ̀ Lu Ààrẹ Tinubu

Ẹgbẹ́ oṣelu All Progressives Congress (APC) ní Ìpínlẹ̀ Osun ti gbà àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ilé igbimo aṣòfin ti Peoples Democratic Party (PDP) wọlé sí ẹgbẹ oṣelu APC ní ìpínlẹ̀ náà. Nígbà tí ó ń sọ̀rọ̀ níbi àsè ní Osogbo, ní ọjọ́…

A Kò Ní Jẹ́ Kí Ẹnikẹ́ni Tẹ Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Mọ́lẹ̀ Mọ́ – Makinde Kéde

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti kéde wí pé òun kò ní fi ààyè sílẹ̀ kí ẹnikẹ́ni tẹ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP (People's Democratic Party) mọ́lẹ̀, fun ẹgbẹ́ míràn láti wà lórí ipò àṣẹ. Makinde ló sọ ọ̀rọ̀ yìí di mímọ̀ lásìkò tó n ṣí ilé ẹgbẹ́…

PDP Gbé Ìgbésẹ̀ Láti Parí Ikùn Sínú Láàrín Àwọn Ọmọ Ẹgbẹ́

Ẹgbẹ́ Òṣèlú 'Peoples Democratic Party PDP' tí bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ láti yanjú àwọn ikùn sínú láàrin àwọn ọmọ ẹgbẹ́, bí Ìgbìmọ̀ Àwọn Olóòtú (BoT) àti Ìgbìmọ̀ Àwọn Iṣẹ́ tí ẹgbẹ́ náà ṣe ń ṣé ìdánilójú ìṣọ̀kan, láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ìdájọ́ ilé-ẹjọ́…

Ilé Aṣòfin Èkó Sẹ́ awuyewuye Ìròyìn Kan Pé, Wọ́n Fẹ́ Ra Ilé Ní Abuja Àti Ọkọ̀ Olówó Iyebíye.

Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó ti ṣẹ́ awuyewuye ìròyìn kan pé, àwọn fẹ́ ra ilé fúnra àwọn ní ìlú Abuja àti ọkọ̀ olówó iyebíye. Nínú ìpàdé ìjíròrò Ilé Aṣòfin náà lọ́jọ́ Bọ (Thursday) ní wọ́n ti bẹnu àtẹ́ lu ìròyìn tó ń fò…
button