Browsing Category
ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GÌN ÀTI ÀYÍKÁ
Ìjọba Àpapọ̀ Ti Gbáradì láti Mú Ìgbòòrò Bá Ètò Ọ̀gbìn Àti Kárà-kátà Ní Àwọn…
Ìjọba Àpapọ̀ ti fi ìgbáradì rẹ̀ hàn láti mú ìdàgbàsókè bá káràkátà àwọn ohun ọ̀gbìn ní àwọn ìletò gbogbo àti ní ẹṣẹ̀kùkú láti ara àlàkalẹ̀ ètò ìjọba fún àseyorí aláìlẹ́gbẹ́
Sẹ́nétọ̀ Aliyu…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kebbi Se Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Àgbẹ̀ Alábomirin
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kebbi ti se ìfilọ́lẹ̀ síṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn àgbẹ̀ alábomirin tí ó lé ní ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dóógún, èyí tí ó wáyé ní ìlú Gulunbe, lójúnà àti jẹ́ kí oúnjẹ wà lọ́pọ̀ yanturu tí yóò sì jẹ́…
Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano Kéde Ìfura Lórí Àìsàn Tó Ń Ja Ẹyẹ Abìyẹ́
Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano ti kéde Ìfura fáráyé lórí àìsàn-Avian Influenza (AI) tó ń ja Ẹyẹ abìyẹ́ tó bẹ́ sílẹ̀ ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Gwale ìpínlẹ̀ náà.
Kọmísọ́nà fún ètò ọ̀gbìn àti ohun àlùmọ́nì, Dókítà Danjuma Mahmoud ló sọ èyí…
Nǹkan Àmúyẹ Ní lílo Àwọn Ohun Èlò Ìgbàlódé Láti Sàmójútò Ọjà Jẹ́ láwùjọ- Ibijokẹ…
Ayá Gómìnà Ìpínlẹ̀ Eko, Ọmọ̀wé Ibijọkẹ Sanwo-Olu ti rọ àwọn adarí ọjà gbogbo ní ìpínlẹ̀ Èkó láti lo àwọn ohun èlò ìgbàlódé fún ìdàgbàsókè àti àmójútó kí wọn sì rí i dájú pé gbogbo àyíká mọ́…
Ìfi Ariwo Díni Lọ́wọ́ Lòdì Sí Òfin Ní Ìpínlẹ̀ Eko- Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó Sọ̀rọ̀ Sókè
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Eko ti pàṣẹ wípé kòsí ìgbàláàyè fún fífi ariwo dí ará ìlú lọ́wọ́ síwájú, lásìkò àti lẹ́yìn ọdún kérésì-mesì
Gẹ́gẹ́ bí ìjọba se sọ, ìgbésẹ̀ náà yóò dènà ìpalára tí ariwo…
Lórí Ọ̀rọ̀ Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Àwọn Ohun Ọ̀sìn, Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ogun Pè Fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀…
Akọ̀wé àgbà fun ẹka ètò ọ̀gbìn ni ìpínlẹ̀ Ogun, Arábìnin Kehinde Jokotoye ti pè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàrin àwọn adaran àti àwọn alámòjútóó nípa ìlera ohun ọ̀sìn fún ìkẹ́sẹjárí ètò abẹ́rẹ́ àjẹsára fún àwọn…
Àjọ Àgùnbánirọ̀ Ṣe Ìfilọ́lẹ̀ Ètò Gbingbin Igi Ní Ìpínlẹ̀ Plateau
Awọn Àgùnbánirọ̀ to wa ni ìpínlẹ̀ Plateau ni àwọn ti ṣetan lati se atilẹyin fún ìdàgbàsókè ojú ọjọ́ ìdí nì yin tí àwọn fi bẹ̀rẹ̀ gbíngbin igi káàkiri ìpínlẹ̀ náà
Alákóso àwọn Àgùnbánirọ̀ ni ìpínlẹ̀ náà ọ̀gbẹni Iliya Yavala lo ṣe ifilole…
Ìrọ̀rùn Dé, Ọ̀wọ́ngógó Oúnjẹ Yóò Dẹ̀rọ̀: Àwọn Alẹ́nulọ́rọ̀ Fọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú Ìjọba…
Lójúnà àti mú kí oúnjẹ pọ̀ yanturu ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àwọn ilé iṣẹ́ kan ti dìde ìrànlọ́wọ́ fún ìjọba àpapọ̀ láti jẹ́ kí ìlérí náà wá sí ìmúsẹ nígbà tí wọ́n jẹ́jẹ̀ẹ́ láti se ìrànlọ́wọ́ fún àwọn…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kebbi San Owó Fún Àwọn Ti Yòó Ṣe Àtúnṣe Àwọn Pópónà Ìgbèríko.
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kebbi ti san Mílíọ̀nù Mẹta ole ni àádọta Náírà fún àwọn òṣìṣẹ́ (RAAMP) ti yóò ṣe àwọn pópónà ìgbèríko.
Alhaji Shehu Mu'azu tó jẹ Kọmísọ́nà fún ètò ògbìn àti iṣé ìgbèríko lo sọ èyí di mímọ ní ọjọ́ ajé ni kebbi nígbàtí o n…
Ìmọ̀ Nípa Ìyípadà Ojú Ọjọ́ Se Pàtàkì Fún Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́- Alẹ́nulọ́rọ̀ Kan kégbàjarè
Mallam Nurudden Bello tí ó jẹ́ alákòsóo ilé ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ètò ìlera ní ìpínlẹ̀ Kaduna ti sàlàyé pàtàkì ìmọ̀ nípa ìyípadà ojú ọjọ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lójúnà àti tán ìsòro tí ìsẹ̀lẹ̀ náà ń mú bá àwùjọ…