Browsing Category
Ìròyìn Ẹ̀kọ́
Àjọ NELFUND Bẹ̀rẹ̀ Pinpin Owó Àlàkalẹ̀ Ti Oṣù Kẹrin
Àjọ Nigerian Education Loan Fund (NELFUND) ti bẹ̀rẹ̀ pinpin Owó ẹ̀yá àlàkalẹ̀ ti Oṣù Kẹrin ọdún 2025 fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó peregede fún un jákèjádò Nàìjíríà.
Àkọsílẹ̀ láti ọdọ Alakoso àjọ Strategic Communications owó náà, Ìyáàfin Oseyemi…
Àtúntò Ètò-Ẹ̀kọ́ Ààrẹ Tinubu Fún Ọjọ́-Iwájú Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́
Bí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gbé ìgbésẹ akin lórí àtúntò Orílẹ̀-èdè, ìṣàkóso Ààrẹ Bola Tinubu gbé ètò-ẹ̀kọ́ àti ìdàgbàsókè ọgbọ́n sí ọkàn nínú èro ìyípadà àti àtúntò rẹ̀.
Ètò ìmúlò Ètò-Ẹ̀kọ́ lábẹ́ Ètò Ìrètí Túntún ṣé pàtàkì ànfàní, ètò…
Nàìjíríà Fìdí Ìfaramọ́ Rẹ̀ Múlẹ̀ Fún Ètò Ẹ̀kọ́ Ọ̀dọ́mọbìnrin
Mínísítà fún Ìpínlẹ̀ fún ètò Ẹ̀kọ́, Ọ̀jọ̀gbọ́n Suwaiba Ahmad, tí tún ṣé ìdánilójú ìfaramọ́ tí ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà látí fí àgbàrá fún àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin Nàìjíríà nípasẹ ìsopọ̀, ifọkanbalẹ àti ètò ẹ̀kọ́ tó dídára.
O ṣé ìdánilójú yìí…
Ìdìbò Ọdún 2027: Ẹgbẹ́ Òṣèlú Labour Party Kòní Darapọ̀ Mọ́ Ẹgbẹ́ Mìíràn
Ẹgbẹ́ Òṣèlú Labour Party ti sọ pé àwọn koni darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ míràn ninu ìbò gbogbogbòò ọdún 2027.
Èyí jẹ ọkan lára kókó méjìlá àlàkalẹ̀ ìpinnu níbi Ìpàdé National Executive Council (NEC) ti wọn ṣe ní ọjó Ẹtì ní ìlú Abuja.
Nigba ti o ń…
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ró Ilé-ìwé Ẹ̀kọ́ Gíga Kọ́lẹ̀gì Lágbára Láti Máa Gba Oyè “Bachelor’s…
Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti bẹ̀rẹ̀ ìmúsẹ Oníbejì èròngbà Ilé-ìwé Ẹ̀kọ́ Gíga Kọ́lẹ̀gì àpapọ̀ káàkiri Nàìjíríà - "Federal Colleges of Education (FCOEs)" latari ibuwọlu ètò ọdún wọn ọdún 2023 - "Federal Colleges of Education Act,…