Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ NSCDC Ti Gbáradì Láti Pèsè Ààbò Tí Ó péye Lásìkò Ọdún Kérésì Ní Ìlú Abuja

Ọ̀gá Àgbà Àjọ Ẹ̀sò Aláàbò Ìlú (NSCDC) Olusọla Odumasu ti pàṣẹ pípèsè ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ọmọ àjọ náà láti dáàbò bo ìlú Abuja àti àgbègbè rẹ̀, ati láti rí i dájú pé nǹkan lọ ní ìrọwọ́-rọsẹ̀ lásìkò ọdún…

Olurẹmi Tinubu Se Bẹbẹ Nípasẹ̀ Síṣe Ohun Ribiribi Fún Àwọn Aláìní- Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kaduna…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kaduna, Uba Sani ti gbóríyìn fún Sẹ́nétọ̀ Olurẹmi Tinubu tí ó jẹ́ aya Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà látàrí pípèsè Ohun iyebíye fún àwọn aláìní láwùjọ   Gómìnà Sani sàpèjúwe Olurẹmi…

Ilé Ẹjọ́ South Korea Bẹ̀rẹ̀ Ìgbésẹ̀ Lórí Ẹ̀sùn Èyí Tí Ó Pè Fún Ìyọnípò Ààrẹ Yoon

Ilé Ẹjọ́ ti bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ lórí ẹ̀sùn kan èyí tí ó pè fún ìyọnípò Ààrẹ Yoon Suk Yeol ẹni tí o ti yẹ̀bá kúrò lórí ipò fun igba díẹ̀ látàrí wahala ọ̀rọ̀ òfin tí ó  wáyé, èyí tí ó ti da rúkè-rúdò sílẹ̀…

Ààrẹ Tinubu Pàrowà Sí Àwọn Akọ̀ròyìn Fún Ìfìdímúlẹ̀ Sinsin Ìjọba Tiwa-n-tiwa

Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti pàrọwà sí àwọn oníròyìn láti sa ipá wọn lójúnà àti rí i dájú pé ìjọba tiwa-n-tiwa fìdí múlẹ̀ sinsin   Àrọwà náà wáyé níbi ayẹyẹ ìfúnni lámì ẹ̀yẹ, ẹlẹ́ẹ̀kejìlélọ́gbọ̀n iru…

Ìjákulẹ̀ Dé Bámi Lórí Ètò Ẹ̀kọ́ Látàrí Ìsàfẹ́kù Owó Péréte- Ice Prince Sàlàyé…

Gbajúgbajà akọrin Panshak Zamani, tí gbogbo ayé mọ̀ sí Ice Prince ti sàlàyé ìpèníjà àti àwọn ìsòro tí ó kojú ninu ìgbé ayé rẹ̀ látàrí ìpàdánù àwọn òbí rẹ ati bí àwọn ìpèníjà náà se jẹ́ atọ́nà èyí…

Lórí Ọ̀rọ̀ Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Àwọn Ohun Ọ̀sìn, Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ogun Pè Fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀…

Akọ̀wé àgbà fun ẹka ètò ọ̀gbìn ni ìpínlẹ̀ Ogun, Arábìnin Kehinde Jokotoye ti pè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàrin àwọn adaran àti àwọn alámòjútóó nípa ìlera ohun ọ̀sìn fún ìkẹ́sẹjárí ètò abẹ́rẹ́ àjẹsára fún àwọn…
button